<<90000000>> viewers
<<240>> entrepreneurs in 17 countries
<<4135>> agroecology videos
<<105>> languages available

Sisa okpe oyinbo si orun

Uploaded 4 years ago | Loading

Pupo ope oyinbo lo si n’ baje nitori kpe e o le toju re ju ose kan lo. Nigbati a ba sa ope oyinbo, a le din adanu ku, ki  a si jere owo kpukpo titi ikpari odun. Ninu aworan yii, a o she afihan bi e le sa ope oyinbo gbe kpelu ero gbigbe t’oorun, nitori kpe ona yii ni imototo ati pe owo re ko tun kpo.

Current language
Yoruba
Produced by
NOGAMU
Share this video:

With thanks to our sponsors