Sise ounje kiki ni owo binti
Uploaded 4 years ago | Loading
10:20
E le ra awon ounje ti o ki, to ni eroja kpukpo eyi yoo she iranlowo fun awon eranko yin ki won tete dagba, ki won she wara kpukpo ati eyin. sugbon owo awon ounje wonyi kpo. Bawo ni a she le see awon ounje gidi to ki fun arawa ni kpoku lowo e?
Current language
Yoruba
Produced by
AIS, MSSRF, WOTR